The Lord's Prayer "Adura Oluwa" Songtext

Übersetzung nach:en

Adura Oluwa

Baba wa ti mbẹ li ọrun;Ki a bọ̀wọ fun orukọ rẹ.Ki ijọba rẹ de;Ifẹ tirẹ ni ki a ṣe,bi ti ọrun, bẹ̃ni li aiye.Fun wa li onjẹ õjọ wa loni.Dari gbese wa jì wa,bi awa ti ndarijì awọn onigbese wa.Má si fà wa sinu idẹwò,ṣugbọn gbà wa lọwọ bilisi.Nitori ijọba ni tirẹ,ati agbara, ati ogo,lailai.Amin.

Hier finden Sie den Text des Liedes Adura Oluwa Song von The Lord's Prayer. Oder der Gedichttext Adura Oluwa. The Lord's Prayer Adura Oluwa Text.